Bi beeko bamigba bi baba ti fe bi bibeli ti ba
Ani opo ope loye enu omo eniyan toku iseju aaya fun lati di pipa
Abi kini irufe okan to tidi oun igbagbe yio se, so funmi
Odaju awon ti o ti ta teru nipa ti n pamopo pelu paapaa lati gbe baba ga
Pelu amon tele pe ise asekara lori ason ni eyi
Ani ki a dupe lowo owo to n bo ni lati rewerewe ti i di aako yi
Si ara waju ni osan didun ti a muu muu mu titi ti a fungbe lati fisile
Si ara eyin to gbo gidigidi ewuro oko pelu opolopo kikoro sibe pelu adun leyin
Eyi ti a je lati yadanu sibe
Si ara oke - agbo lati mara le sibe yio sise tan oun toye ko teyin igbin yio si fara han
Ah e, ewo o opo oun imo ni a saa tikoyin si ninu aimo!
Iha aramo
Ifireni sinu ide aye nitori ife oun ti o lo lailai
Aye felo bi afefe se n fe fii fii faa faa yii yii
Oun fi wa sile lookokan ejeeji osin diku diedie afefe
Sibe an padi apopo lati se aye bi ose wu wa
Botiwu kope to sora, oun ti a o mo igba ati a gba ma di oun ti a o fisile funra wa
Igba o lobi orere ore, ojokan loun ti a nyin ma doun a ko rimo rara.
Jodekss
©2015